Mo ki yin ku abo si ori ero alata yigba yi, ti gbogbo aye mo si blog. www.SAWOROIDE.blogspot.com, je ise opolo, ti agbe kale fun idagba soke, ede, ise ati asa Yoruba,fun idi eyi, a pinu fun gbogbo omo karo o jire wipe, gbogbo ,iroyin ti won ba ka lori SAWOROIDE, yio je otito ati ododo.lai fi iro si. lati igba de igba, a o ma fun yin ni iroyin. oun to sele lagbo awon osere, iba je ,Olorin,Onijo,Osere ati be be lo. Aye wa fun imoran, awon alejo si SAWOROIDE le gba ni imoran, ilekun ile ise was shi si ile. Olorun A ran wa ni owo.....Naijajuwon oon. oniroyin
No comments:
Post a Comment